Home # 9ice 9iCE – VERSUS (ALBUM) LYRICS 9ice – Iya Alariya

9ice – Iya Alariya

9ice - Iya Alariya on vibes2lyrics.com
9ice – Iya Alariya LYRICS

PLAY MUSIC [sc_embed_player fileurl=”http://www.vb2l.ciki.me/musics/9iceVersus/05%20Track%205.mp3″]

Emi Ni Kakorewa
Mo ni BABA ni igbejo
Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono

Iya Alariya Kenke{x4}

Ti mo ban’lo pelu imo kan,
tabi mo re ko ja lo pelu inu kan,
sha de ‘de ni Blessing awa si o’do mi, tori mo gbagbo
Egbe gberu subu lotun losi mi
Nkan kan ko le se omo Olorun ……

E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo

Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono

Iya Alariya Kenke{x4}

Ise owo mi, koni di ibaje
Bi wan ti e dun mo wuru mo wuru mo ‘mi,
won kon fe te, Baba ti se ileri pe ma je aye mi pe’pe’pe’pe
ate ‘pe le’se n te ono
Ajoke aiye, asake orun….. Ko ni shi mi loo’no
eye se inu binu simi mo, mo ni baba ni igbejo

E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo
E mi nikan kan ni mo ‘wa, mo ni BABA ni igbejo

Mo wa owo lo, mo pade ola ati iyi lono

Iya Alariya Kenke{x4}